Arobayo ! : Gbogbo Egbe E Maa Yo !

ABOUT EGBE

Nigeria

North America

Locations

Ireland

Canada

UK

France

Arobayo ! : Gbogbo Egbe E Maa Yo !

OUR EXECUTIVES

~ANTHEMS~

EGBE AROBAYO ANTHEM
Arobayo le gbe wa,
Arobayo le gbe wa,
Toba batiriwa, ko ma yo ni,
Arobayo yi ti gbogbo wa ni
Ko ma gbogbo baje
Arobayo lo laye, lo laye o
E je kasowopo, Kajumo gbega,
Gbe e e, Kemi gbe,
O tun ya o,
Gbe e e, Kemi gbe,
Le kan si, gbe e e, kemi gbe,
Arobayo… gbogbo Egbe ema yo

AWUJALE ANTHEM
Kabiyesi O!
Kabiyesi O!!
Alaiye Oba Wa
K’ade pe lorio O
Ki bat ape l’ese
K’ Odigba pe l’orun
Ki Oba pe titi
Ki ‘joba tu wa lara
Kabiyesi O, Oba wa
Oba wa oninure
Kabiyesi O!
Kabiyesi O!!
Alaiye daji

 

 

ORIKI OGBAGBA
Omo Ogbagba Agbatewole
Omo Anikilaya Saagun
Omo aloogun sa karakara laja
Omo aitetegbo ologbo nii iya
Bo ti’ape titi a teku u paje
Omo abebejoye
Omo ta a be koto joye baba e
Omo a niee bo lehin o naira wa ju
Omo alara gbadamugbadamu
Omo Anihun toyinbo o ni nle
Oyinbo olosa
Omo gboko gbala

Brooklyn, Ijebu 10036

arobayookunrin@gmail.com

+234-802-314-4696

#arobayos